Eto Isuna Cryptocurrency Ni Irorun

in #yoruba4 years ago (edited)

Titele ipase baye ba se n yi, kama bawon yi ni ona to daraju lati ma se deni igbagbe seyin.

Ninu eka eto inawo toloyinbo npe ni Cryptocurrency, a ti sun kuro ni nilo lati se iforukosile ki a to le yi owo pada.

Oniruuru wahala lo ma n jeyo bawon eyan ba fe yi owo pada tabi tawon eyan ba nilo lati na lara dukia tabi ohun ini won nibi ti won o ti nilo lati se oniruuru ipele iforukosile KYC. Sibe, pelu gbogbo wahala iforukosile KYC yi, o tun seese ki o ma kese jari latari awon iyato die die to ma n jeyo lakoko iforukosile bii ki irun to wa ninu aworan ti elomi ya, ko yato si bohun fun ra re se ri

Sugbon ninu eka eto inawo Cryptocurrency, ko nilo gbogbo wahala yi, abo to peye si wa fun gbogbo ohun to banise pelu re.

Ni awon orileede bi ti Nigeria, fun apere, oruko to n be lori iwe isanwo ina lee yato si oruko awon to n gbe ninu ile tiwon ti n fi iwe na sanwo ina tori pe won ya ile na gbe ni, kii se ile won. Bi enikeni ba fe se iforukosile pelu iru iwe bee, oseese kawon ile ifowopamo ma gbaa nitoripe kii se oruko onitohun lon be lori iwe isanwo ina ohun. Bee sire awon ile ifowopamo tabi ile ise eto isunna ma n fariga pe dandan ni ki gbogbo iwe yi ati oruko eni to fe yo owo, ki o bara mu.

Oo se ye dara re lamu pelu gbogbo wahala iforuko sile yi?

Itakun ero ayelujara https://changenow.io ni mo n lo mo si n gbadun re daada. Opolopo eto owo ni mo ti se lori itakun ayelujara yi lai mu wahala kankan dani.

Eyi ni itakun ayelujara akoko to n ri s'oro eto inawo Cryptocurrency to fun mi l'anfani lati se ohun gbogbo ti mo fe se lai si gbogbo idamu iforukosile kin to le ri ohunkohun se.

Sugbon lati pinwo awon oni jibiti, tabi ti nkankan ba mu ifura dani ti ChangeNow si sawari re, oseese ki Iforukosile KYC di dandan.

Changenow ni awon ohun elo anfaani bii,
Changenow academy, eyi je agbekale ti a da sile fun lati ran awon eniyan lowo lati mo ohun ti o n je owo crypto .Ile ise yii wa ni aye to Dara a si tun maa fi Kun opolopo awon akoonu ati awon eya Ara ero bi asiko se nlo e let sabewo https://nowacademy.io lati beere eko ni perewu.

Changenow affiliates , Ile ise iyipada eleyi je eto ti a gbekale fun awon onibaara lati je anfaani lopolopo. Fun gbogbo onibaara ti o ba mu wole nipase ona asopo ti a fun o, wa ri idapada pasenti 0.4 ninu awon eto oro aje won.

Changenow payments , eleyi je ona ti o rorun ju lati gba owo crypto. Ele gba wo crypto bii Bitcoin, etherum,stablecoin ati bee bee lo pelu changenow payments nisisiyi. Lori ala re, lati lo eto siso e lo si https://nowpayments.io lati beere.

Nownodes , eleyi wa lati beere isowo.
Awon olutayo owo crypto ati awon akeeko ti won feran lati ri iraye si awon owo koinsi,'public nodes' gbangba lalai ni lati fi owo sile so fifilele awon bi nodes ti won.
Ti o ba feran lati lo awon Nownodes https://nownodes.io je aye to dara fun o.

Coin Marketplace

STEEM 0.20
TRX 0.14
JST 0.030
BTC 68168.17
ETH 3256.43
USDT 1.00
SBD 2.67