Ojuse awon obi si awon omo (The responsibility of parents to children)

Ojuse awon obi mejeji ni lati fowosowopo lati toju awon omo won fun apere:

  1. Nipa eko iwe
  2. Nipa eko ile
  3. Nipa eko oro olorun
    Igbe aiye awon obi gbodo je awokose fun awon omo won obi gbodo fun awon omo ni ogun ti won, eyi ni lati to omo nile iwe de oju ami, tabi lati ko owo fun won lati se owo. Eyi yio mu ki ojo ola awon omo wa dara. Iya ni o maa nsaba faramo omo ni ile julo, iya omo gbodo ko awon omo.

Fun apere: 1. ise ile sise 2. bi a ti bowo fun awon agba 3. bi a ti se nlakaka lati di eniyan pataki nipa iforiti ati ifarada, bi a ti se nje ajeyo, ati bi a ti se nwa laije Prov.22.6

Awon obi ko gbodo maa mu awon omo binu bi Efesu 6:4 bi kose lati maa to won, papa ni ona olorun, awon obi gbodo kan nipa fun awon omo lati maa lo sile olorun. Won gbodo ko awon omo ni adura gbigba, bi awon omo yi bati mo Olorun, ko ni si ewu fun won ni ojo iwaju yala awon obi won wa laiye tabi won ko si.

iwe mimo wipe to omo re yio si fun o ni isimi awon obi gbodo maa ni akoko adura gbigba pelu awon omo ninu ile ni ale tabi ni owuro. Bakanna a gbodo maa bawon wi Prov.23:13-14

Translation from Yoruba to English

The responsibility of both parents is to cooperate in caring for their children for example:

  1. By learning the book
  2. By home education
  3. By the Word of God
    The life of parents should be an inspiration for their children to give their children as a legacy, which is to send children to the front desk, or to afford them money. This will make our children happy. The mother often sucks the baby in the home, the baby's mother must have children.

For example: 1. Home work 2. How to respect elders. As we have made the effort to become a great person about tolerance and Patience, how we are doing so, and how we are tempted without Proverbs.22.6

Parents should not annoy their children Ephesians 6: 4 as they do so to keep them in the right path, parents should simply ask children to stick to God. Children should be taught prayers, if these children do know God, there would be no danger for them in the future whether their parents are present or not.

The scripture says, Train your child so that your child will give you rest, parents should have time for prayer with your children in the home at night or in the morning. They should also be corrected in Proverbs 23: 13-14

Sort:  

Hello! I find your post valuable for the wafrica community! Thanks for the great post! We encourage and support quality contents and projects from the West African region.
Do you have a suggestion, concern or want to appear as a guest author on WAfrica, join our discord server and discuss with a member of our curation team.
Don't forget to join us every Sunday by 20:30GMT for our Sunday WAFRO party on our discord channel. Thank you.

Coin Marketplace

STEEM 0.19
TRX 0.15
JST 0.029
BTC 63525.26
ETH 2583.76
USDT 1.00
SBD 2.80