@maryfavour SMT Ideas: Àkókò tí ó ńi adùn ńlá ń bò níwájú gégébi Olùdásílè Steemit @ned, se se ìfilò ìfìsílè ìwé atóka Smart Media Token

in #smt7 years ago (edited)

Àkóso

Èrí ìdánilójú fún steem láti jé ìlú mooká tàbí gbajúmò ti gaa si, gégébi olùdásílè (CEO) steemit, Ned Scott @ned ti se ìfilò ìwé atóka ojú ewé aadóta ti smart media token.

Kíni ohun jé Smart Media Tokens

  • Smart media token jé ohun tí óní ye lórí ti èro ayélujára lórí èro tí kò ní àsírí ti steem tí oníkúlùkù le sàgbékàlè láti so ohun tí won bá n se lóri èro ayélujára di owó àti láti sèdá ìfi nkan fún ni tí ó lè se ìgbòríyìn fún eni tí won bá fé

  • Wón dàbí Ethereum’s ERC-20 tokens, sùgbón èléyì ni èrí opolo tí a se sí inú rè gégébí àpèjúwe àti ìfi token se èrè fún ni tí a se lótò fún káràkátà lórí èro ayélujára

Orísun: https://smt.steem.io/

Kíka ohun tí a ko sí inú ìwé atóka ti SMT, mo ri wípé èléyì jé ànfàní ti òpòlopò ti ńdúró dè, Smart Media Tokens (SMT) lè jé idábù fún Ethereum's ERC-20 tokens, ní gbà tí a bá se ìfìlólè rè ní 2018 . Èléyì jé èròngbà mi, máa di òrò mi mú.
Jòwó kaa àwon àpèjúwe tí a lè fi èléyì se níbìyí àti ìwé atókasí. Tí o ò bá ní òye ohun tí a ń pè ní èrí opolo, ka ojú ewé kínní ti ìwé atóka ti steemit láti ní òye kíkún

Wo amóhùnmóàwòrán @ned tí óní kí a pín fún ara wa láti ibi ìgba òhùn àti àwòran sílè youtube ti @jerrybanfield

Atóka: Mo sáré ka ìwé atóka SMT. Mo lérò wípé mo maa kaa síwájú si láti ní ìmò kíkún, àti dáhun ìbéèrè fún ìmòdájú àti òye ohun titun yi. Steem maa loo òkè!

Kíni ohun tí ówà lókàn re lórí ìfilò ti smart media tokens (SMT)?. Jòwó, bámi sòrò ní àyè ìdáhùnsí tí ówà ní ìsàlè. Mo fé gbó láti òdò re.

Esé púpò



The original version of this translation is found here.

https://steemit.com/steem/@maryfavour/exciting-times-ahead-as-chief-executive-officer-of-steemit-ned-announces-release-of-smart-media-tokens-smt-whitepaper

Appreciation goes to @maryfavour for assenting to the translation of her thoughts on the SMT





Sort:  

Nice work fellow steemian, this looks like hard work. Translation is always hard work, as most translators strive to not lose the contents of the original message. Keep hope alive. Keep steeming.

Thanks mate. Its hard and fun. lol. I try my best to keep them in line always. Someday someone is going to find it useful.

I bet, ran into a useful post done last year here.

Really, that brightens my day. Thank you @greenrun. Always running into good stuff

There is a lot of it around. Hard not to run into them 🙂

Good job mate

Haha..
Well done brother
Hope you would start translating to igbo.. ;-)

Congratulations @turpsy! You have completed some achievement on Steemit and have been rewarded with new badge(s) :

Award for the number of comments received

Click on any badge to view your own Board of Honor on SteemitBoard.
For more information about SteemitBoard, click here

If you no longer want to receive notifications, reply to this comment with the word STOP

By upvoting this notification, you can help all Steemit users. Learn how here!

You really doing great bro. Well-done sir...

Coin Marketplace

STEEM 0.19
TRX 0.15
JST 0.029
BTC 63178.17
ETH 2581.50
USDT 1.00
SBD 2.71