Steemit in yoruba translation! Itumo steemit ni ede yoruba!

in #languages7 years ago

Steemit ni awujo ero alatagbo ti olukulu eniyan ti n pade arawon kaakiri aye, orisi ona ni a fi n lo awujo yii. Ibi ti a ti n fi aworan, imo, iriri, isele ati o un ko un ti a le ronu ni pa. Gbogbo eyii kii se lasan, ere tabi ebun ti a n pe ni rewards wa fun Eni ti o fi sowo si awujo yii ati eni ti o digbo (vote) lori n Kan ti afi sowo yii. Awujo yii kii se fun ilu Kan tabi orile ede Kan pelu, Gbogbo agbaye ni awujo yii ti tan de. image
Steemit yi o ni ere ni ninu pupo, Maa so die ninu wonyi: ere owo(STEEM DOLLAR)
agbara steem (STEEM POWER)
Owo Steem yii si wulo ni orisi ona, o je itewo gba ni gbogbo agbaye, beeni a le fi ra owo isowo (cryptocurrency).
image

What I actually explained in yoruba is just summarize in English below ;
Steemit is a social community that is broadcasted through the globe 🌏, it is not just for a state or country, it's very much different to other common social communities out there, enough of benefits attached to this community steemit, monetary rewards cannot be skipped. This is in two dimensions, both the poster of any post and the viewer or the upvoter are rewarded.
Two different major rewards are Steem Dollars and Steem power. The Steem Dollars is widely essential, it is tradable at any time for cryptocurrency e.g Bitcoin, ETHEREUM, etc.
This is just a tip of my submission on steemit for now. Kindly Upvote, follow @mikestynson, comment & resteem.
Thanks for reading.
image

Sort:  

wonderful post keep promoting steemit and together lets steem on!!!!!!

Coin Marketplace

STEEM 0.31
TRX 0.26
JST 0.040
BTC 97807.69
ETH 3616.29
USDT 1.00
SBD 3.38