Ifíhan Àwon Àwòrán Orí Oko

in #agriculture6 years ago

Èní yí je ojúmó ire. Ifíhan Awón Àwòrán Orí Oko sí n tè síwájú ní kíkún .

Akosílè yìí je ònà làti se ifíhan awón eso at eere orí oko wa tí áyà pèlú ohun áyàwòràn ero ìbánìsòrò waa.

Àwòrán eso tá a fé se afíhàn rè léní ni igi ìbépe orí oko wa .


IMG_20190211_102731.jpg


Mo ya àwòrán yìí pèlú Ohun aya àwòrán èro ìbánisòrò Blackberry Q10 .

Coin Marketplace

STEEM 0.19
TRX 0.15
JST 0.029
BTC 64176.22
ETH 2624.19
USDT 1.00
SBD 2.78