Jíjé Ologbón pèlú Smart Media Tokens: Àyèwò fínífíní mi fún gbogbo ònkàawé

in #smt7 years ago


Òrò àkóso



Wo àkàwé yii, jé èró aayé lujára tí ó ní ibi ìpàmósí bi ti Facebook pinu láti se ìwúni lórí fún àwon ònkòwé rè, ìsòro nlá yí ò selè, nítorí wípé kò sí òpò láti kárí gbogbo.

Ní ìdánu lójú a lè lérò wípé wón maa n ri owó láti ìpòlówó ojà, sùgbón eléyi kò tó nítorí wípé léyin tí wón bá ti rí èrè tó poo, won kò ní ní àjesékù láti kárí.



Ní bà yíi ònà àbáyo ti wà... Smart Media Tokens



Ní àwon orò tí ó rorùn láti mò, smart media token jé ètò tí ó nfi fún ni tàbí owó tí a se fún ìfi fún àwon tí óhún sèdáa onírúurú àti àwon tí ń se àyèwò agbègbè kòkan.

Pèlú òrò tí mo ti ko séyìn, eléyì jé ohun tí a se lójò láti yí ojó òla ohun tí a bá sèdá ní orí èro ayélujára. Fojúinú woo tí o bá rii pé ó rorùn láti sanwó tàbí fún elòmíràn ti e jo wà ní ìpéjopò kan ní èrè ohun tí gbogbo ni ìfé sí.



Ní ìsòrò sí wájú sii, a sè èdá eléyì ní orí èro tí kòní àsírí ti steem, eléyì túmò si wípé, smart token yi ó fún èro tí kò ní àsírí ní agbára béeni yí ó sì ní àmì ní orí ojo òla iso nkan di owó lórí èro ayéelujáara

Èyí túmò sí pé steem yí ò jìjà gbàra làti wàa ní ìpò kínní ní orí coin market cap, pèlú gbògbo ànfaàní láti mú gba orí lówó bitcoin.



Léyìn ìfitóni létíláti owó @ned, ariwípé eléyì se ìrànwó fún owó steem, àwon owó ayélujára tí oó maa ń wà ní ipò kínní sí ìkèwá ń lolè, sùgbón steem ńlo oké.







Mo so nípa steem láti gba orí àbí? Òkan nínú ohun tií ómú bitcoin láti gba ojúmò ni wípé a ń lo fún òpòlopò nkan, eléyì túmò sí wípé, a lèe fi sanwó ile igbáfé, owó ohun tí a yá, sodi ojúló owó, àti beebee loo.

Smart media token se eléyì ní onà míràn, ohun lo èro tí ó ní steem gégé bi ìpìnlè, àwon èro kékèké tàbí èro ayeélujára tí a sèdá lórí rè lee sèdá àwon nkan tí a le fi fún àwon omo egbé wa ní èrè, eléyì ni a máa ń pè ní èrí tí opolo.



Smart media token tí a sèdá yi kò sí ní ikáwó énìkan kan láti máa fí aàyè gba ìdìrú `ati àwon màgòmágó, a máa ń pe eléyí ní algorithm tí o sopò móo èro ayéluujára tí o dè siì maa n so di owó.

Ohun kan ti ó léwà



Ohun tí o dára nípa Smart Media Token ni pé ó rorùn láti lòo pèlu onírúurúu èro ayé lujárá, ní pàtàkì jù lo àwon tí óní ìbi-ipámó si, àpèjúwe, ti orú ènìyàn bí Paris Hilton báá loo ìsètò yi láti pín èrè fún àwon ontèlé rè tí ó pò.



Mo lo àkókò tó po láti kaa smt pdf whitepaper, síbè mo sì tún sàlàyé ohun tí a ti so ní àwon òrò tí ó rorùn láti yé ni.

Alè se àpèjúwe rè gégébi èro tí a fi ń fi nkan ránsé, a lè ní onírúrú ibi, asì le fún àwon sòròsorò tí ó bá wá níbè ní steemit chat token.

Tani òrò yí kàn?



Gbogbo ènìyàn ...

Olúkúlukú eni ti ó bá ń se dáadáa ní òròsíso nínú egbé níkan naa yí ò ní `anfàaní láti jèrè nínú egbé múdúró tí a ń pè ní smart token media bí ó ti jé wípé yío le gbaa èrè púpò láti owó eni tí ó sèdá àwon ìsanwó fún ni yi, gbogbo eléyí yíò sèlè lórí èro aani àsírí ti steem.



Tí gbogbo ènìyàn báa bèrè sí ní lo èro yi, oye tí á n ta steem maa losókè. Eléyí jé ìmúse àlá, tàbí èrò ńlá ti Kérésìmesì tí ó ń lo ògùn olóró àti ìgbéláruge ti nitro.

Láti jé kí èyí selè, ohun àkókó ni láti ní àpò pèlú steem. Àwon nkan míràn waa tí ó n se atókùn fún lílo àwon àpò yí.



Yàtò sí wípé ìwé nàa jó ohun tí ó gùn àti àwon ìpàróje, gbogbo nkan tó wà níbè see déedé, sì rántí wípé, eléyí ni èdà smart media tokens ní òrò tèmi àti ní òye tèmi

Tí o bá fée wòo ìkàsílè ti móhùnmáwòrán ti ìfilò smart media token tó mo rí ní orí ibi n ko n kan sí ti @ned, ó wà ní ìsàlè yí.





Ohun tí ó see ìyàlénu jù fún mi ni ìsòrò ní bí ó se lè yé ni, ìdí tí à fi sèdá rè, èyí ni ìkásílè ti móhùnmáwòran láti ibi n ko n kan sí rè.





Rántí láti wà ní ìṣèlè Steemit Ni Nigeria

Eléyí jé ìtúmò ní èdè yorùbá fún àkòsílè ti @ehiboss. Ojúlówó àkosílè yi wà ní ibí yi
https://steemit.com/steemit/@ehiboss/getting-smart-with-smart-media-tokens-my-review-dissected-for-all-readers

Mo dúpé lówo @ehiboss tí ófún mi ní àse láti túmò èyí ní Yorùbá.

Sort:  

Omo ìyá, orí e pé lópò... Haáhaàhaá... Èyí pò

Too much sauce. Glad to see people promoting Yoruba language.

It's our property it shouldn't be left un-promoted

Nothing is more interesting and pleasing to the eye than seeing a fellow Nigerian that is able to write an article in their dialect.

I may not understand yoruba, but I really admire this gesture. keep it up bro @turspy

I dont get your words but l like the presentation...you have a message...@turpsy ..upped

@mcsamm sorry if you dont get it. Its a Yoruba translation of @ehiboss smt post. Thanks for stopping by.

Mo feran bii e ti se atupale gbogbo iroyin nipa SMT yi. O sowan lati ri eni ti o le se bee .
Ami ti otun wa ni ibe lasan o wu mi lori pupo.

Mogbe osuba kaare fun yin

Hahaha. This is great. I perfectly love your response.

Waw! This is wonderful. I wont tell a lie, I couldn't read all, but thus is a very bold step to be able to tanslate the SMT into an indigenious language. Well done. Well done dear. You did justice to this work.

Thank you @gloglo for reading. Languages are.as important as the content being passed across.

Jesus, your abilities are creepy. Yes, creepy is the word.

This is good!

Hahaha, Thanks @gunneresq.

You are welcome bro.

Eku sę o @turpsy
Mio gbo yooba daa daa sugbon mo gbo nkan ti ę so die. Ayo STEEM media tokens a Kari o.

Laughing, don't mind my fake Yoruba o.


@learnandteach01

Hahaha, amin ooo

That's lovely. Our local languages should be promoted.

yes, you are right. there is @udochiokeke that does igbo languages too

Guy! I have to legitimately say this...You're f**king awesome! I don't understand a word (because am not Yoruba) being patriot, I am proud when i see others doing great things with our heritage.

Respect bro!

I followed and upvoted you, do check out my posts and follow back.

PS. I resteemed the post too!

Coin Marketplace

STEEM 0.30
TRX 0.11
JST 0.033
BTC 64243.42
ETH 3152.93
USDT 1.00
SBD 4.28